|
Ipá ọ̀na ẹ̀kọ́ wa yoo fún yin ni ojúlówó ohùn eló. Ìlé-ìwé wa ńse ìdánílẹ́kọ́ níèdè Faransé, Gẹ̀ẹ́sì, Yorùbá, Larubawa, èdè Spéènì àti bẹẹ bẹẹ lọ...
Èto wa lẹ́sẹ́sẹ
Ìlanà
Ènìyàn láti ní opin ẹ̀kọ̀ iha ìlà oòrùn.
Ìlanà wa ni èsì odún ọdún mẹ́wa ti ìrírí ìwúlò atí ẹ̀rí àṣeyọrí.
Iyára ìyọrísí ìré
Ní ilé-ẹ̀kọ́ àkọ́mọ̀lédè ATT Communication, ẹ kọ bí a ti ṣe ńjùmọ̀ ní ọ̀na ìbáṣepọ̀ ìwádi ìmọ̀, ìlò ọ̀rọ̀ dajúdajú àti iwé àgbédègbẹ́yọ̀ ni ti otitọ, ọ̀rọ̀ ti o ṣiwájú, ti o si tẹ̀lé awọn ọ̀rọ̀ pàtàkì nínú iwé ti a ńka lọ́wọ, láti túmọ̀ rẹ pẹ̀lu ̀ìyànjú,eyi ti o kere jùlọ̀ iwà ìrọrùn lilò.
Ìgboòrò Èto lẹ́sẹ́sẹ, ẹ̀kọ́ wa àt́i ìkọni aránṣọfa wa, ni látí tèyin lọ́rùn àtí pé ohùn tí ẹ fẹ́ wá ni ìdásilẹ̀ dédé àti mọ̀ o yeé.
Akọ́wa látí lò akanṣé ìmọ̀ pàtàkì àti ìṣẹ́ ìjinlẹ̀ ìkẹ́hin, ìlọsíwájú rẹ̀ leralera,pẹ̀lú olùrànlọ́wọ́ olụ̀kọ́, èsì ẹ̀rí ìwà ijánu. |
|
Ìdánilẹ́kọ́ Tó Lágbára
- Ẹ̀kọ́ Faransé, wà ni akójọpọ̀ kékeré ní ìwọ̀n akẹ̀ẹ́kọ́ bi mẹẹ́fà
- Kíkójopọ̀ akẹ̀ẹ́kọ́ pẹ̀lú ìṣọ́ra wa, lórí oye èdè ẹni Kankan
- Ẹ̀kọ́ jẹ́ ohùn idáraya, ọ̀pọ̀ ìkópá akẹ̀ẹ́kọ́ , ilọ́wọ́wọ́ atí àyíká tí ó fanimọ́ra
- Awọn olùkọ́ wa, ní ilọ́síwájú nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀-èdè, wọn sì tún dangajía nínú èdè Faransé. Wọn ní ìrírí gbígorò nínú èdè, wọn sì tún mọ̀ èdè gẹ̀ẹ́sí atí èdè spéèní gẹgẹ bi èdè wọn kéjì.
- Aláṣàpúpọ̀ atí onítara ẹ̀nìyàn ni àwọn olùkọ́ wa,. Wọn gbadùn pínpín atí kíkópá nínú oríṣiríṣi àṣà
Ìlọsíwájú Kánkán
- Ẹ̀kọ́ làárin akójọpọ̀ kékeré kikánkiká pẹ̀lú aṢeyọ̀rí, látarí wípé e o ní wàkátì kan àábọ̀ nī́nú ìṣẹ́ ṣisé lòójùmọ́
Iyé tí kò Lẹ́gbẹ́
- Gbogbo ohùn eélo ẹ̀kọ́ ni ẹ́ o gba lọ̀ọ́fẹ.
Ìṣẹ́ àmọ̀dájú to dárató
- ìdánwò kí a to bẹ̀ẹ́rẹ̀
- Akójọpọ̀ ìtẹsíwájú ẹ̀kọ́ tí a ṣe
- A nf́ẹ́ ìfọwọ́sọwọ́pọ̀ èési yín atí ìmọ̀ran yín
Iforùkọ́ sílẹ̀ ní ìrọrùn
- Ìforùkọ sílẹ̀ idẹra ni kíakía
- Akẹ̀ẹ́kọ́ lè bẹ̀ẹ́rè ẹ̀kọ́ ĺóṣooṣù
Fún ẹ̀kún rẹrẹ àláyé ẹ jọ̀wọ́, e pè:
ATT Communication
02 BP 2579
Cotonou
Tel:( 229) 66 99 43 05
Orilẹ̀-Èdè Olóminira Benin |
|
|
Èdè Yorùbá jẹ́ èdè akọ́kọ́,fún nnkan bi ẹgbẹẹbẹ̀rún àádọta ènìyàn,ní ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà. Àìmọye ènìyàn ńsọ èdè Yorùbá ní Gúúsù Nàìjíríà, ní Ilẹ̀ olominira Benin, ní Togo àti láàrin ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ àwọn ọmọ adùláwọ́ t́í wọn wà lókè-òkun.
Látàrí iyé awọn ènìyàn tí èdè Yorùbá jẹ́ èdè akọ́kọ́ sọọ wọn,pẹ̀lú ipá títobi tí ọ̀rọ̀-ajé, atí àṣà káàárọ̀jírè ńkó ní ìwọ̀-Áfíríkà, èdè Yorùbá nṣe ifànimọ́ra fún ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ àwọn amòye èdè, àwon oníṣòwò,bákànnáà fún àwọn iĺé-ìṣẹ́ ńla ńla tí wọn máań tà ọjà atí ìṣẹ́ fún ará ilú.
Àwọn ọmọ adúláwọ tí wọn wà nílẹ̀ Amẹ́ríkà, ní àwọn orílẹ̀-èdè bí USA, Brazil, Cuba atí bẹẹ bẹẹ lọ,máań dìgba ṣẹ ẹ̀kọ́ Yorùbá látàrí ifẹ́ tí wọn ní sí orísun wọn. Iyen nítorí wípé,láti ilẹ̀ Yorùbá, ni wọn tà ọpọ̀lọ́pọ̀ àwọn bàbá-ńla wọn lẹ́rú ní nnkan bí ọgọgọrún ọduń méjì sí mẹ̀rin sẹhìn.
Ilé-Ẹ̀kọ́ àkọ́mọ̀lédè ATT COMMUNICATION gbé àwọn ìdánilẹ́kọ́ pípé, kálẹ̀, lórí èdè Yorùbá fún àwọn àlákọbẹ̀ẹ́rẹ̀, àw̄on ẹni tí wọn ní ìmọ̀ díẹ̀, atí àwọn tí wọn tí tẹsíwájú pẹ̀lú ìtẹnumọ́ tí o lágbara lórí pìpè atí fífétísílẹ̀.
A dá Ìwé ìlana ẹ̀kọ̀ Yorùbá wa sílè, láti lè jé kí àwọn àkẹ̀ẹ́kọ́ mọ̀ ọ̀rọ̀ sọ̀,lọ́na àjọṣepọ,kí wọn sì máa kọ̀ ofì-èdè,atí ìlò ọ̀rọ̀ ní òtítọ́.
Ní afìkún sí ẹ̀kọ́ Yorùbá tó péyè, ìṣerélọ sí ilẹ̀ Yorùbá tún wà nínú ètò wa. Ètò ìbùgbé nílé àwọn ẹbí Yorùbá, ti Ilé-̄Ẹ̀kọ́ àkọ́mọ̀lèdé ATT COMMUNICATION yán, sì wà ní àrọ́wọ́tó, lórí ẹ̀bẹ̀. |
|