|
Imoran Lori Igberohinjade
|
|
|
Pàtàkì ìṣẹ́ tíwa ni……. Láti ṣe àṣeyọrí àìnífoiya ìpólowó fún ilé-iṣẹ́,ẹ̀gbẹ́, tabi ìwé ìkawé yín. Yálà ìpólówó, ìmòràn lórí awọn oun-ìgbéròhìnjáde, ìgbélárugẹ awọn ilé-ìṣẹ́,ẹgbẹ́, ìjọba, a dá ìṣẹ́ àṣatúnyẹ̀wò tíwa sílẹ̀ láti lè ṣe ìránlọ́wọ́ fún yín,ki ẹ lé fi-kàn awọn agbo-ènìyàn yín tí o ṣe pàtàkì àti kí ẹ lè jẹ́ àṣíwájú nínú ìṣẹ́ yín. Bí ẹ bá ní ọ̀rọ̀ agbára tí ó bá ofin mú,iṣẹ́ tàbi ìkórè, tí ẹ rí wipé o yẹ kí awọn ènìyàn gbọ́ nípa rẹ,a ṣe tan làti ràn yín lọ́wọ́.
Èrò tíwa ni ……
Láti jẹ́ ki ẹ ní èsì tó lè mú òkìkì, ifẹ́ tí wọn ní sí yín àti aásìkí lọ́ sí wájú. Ìgbélárùgẹ àti ìpolongo lórí awọn oun-ìgbéròhìnjáde tí o yàtọ. Ẹ maa rò pé ìpólówó tó dara tó. Ẹ maa sì ní ìretí pé yoo fa ọpọ̀lọ́pọ̀ ifetí sìlẹ̀ sí ìṣẹ́, ìkórè tàbi ìyọnu yín. Bí awọn oun-ìgbéròhìnjáde ńla ńla bá fowọ́ sí àlàyè èrò-ọkàn yín, tẹ tí fi lọ aṣoju yín, yoo jẹ́ kí ìgbẹ́kẹlé tayé ní sí yín gbé yín dé okè mìíràn tó tẹjú. Èrò tíwa niyen, láti pèsè awọn ọ̀gbọ́n títún lóri ìpólówó ọja,kí ẹ rayè lò awon èrò ọ̀hụ́n pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ awọn oun-ìgbéròhìnjáde to mú-nádókó pẹ̀lú ìgbéga to ńdánilóju àti tó nṣeégbẹ̀kẹ̀lé fún awọn agbo-ènìyàn yín pàtàkì.
Ìpolówó tó jụ̀ ìpólówó lọ
A mọ̀ wa fún akédè imọ̀ṣẹ́ iyàtọ́. Síbẹ̀síbẹ̀, ATT Communication lè ṣe jụ̀ bẹ̀ lọ. A lè ṣe àkọ̀wé, a lè jẹ́ aṣáájú ọlọ́gbọ́n tàbi àṣelọ́pọ̀ ìṣẹ́ fún awọn oun-ìgbéròhìnjáde. A ní agbára láti rídí awọn-ìrètí pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ojú-ìwòye tó jẹ́mọ ọja títa, a sì lè ràn yín lọ́wọ́ láti pèrò ìṣẹ́ ìpolongo pẹ̀lú àjọṣepọ awọn ẹgbẹ́ ẹgbé ,ilé-ìṣẹ́ tàbi ìjọba. Ní afikún,ATT Communication lè
Ipé kanṣoṣo sí ATT Communication yoo ṣí ọ̀nà
Ìránsẹ kan ṣoṣo,fún yín ni anfani láti lè
Ìwé owó ọjà kan ṣoṣo lè
|