Iṣẹ́-wa
Ìtúmo
PDF tẹ ìwé Ijiṣẹ-iwe

Ní ayé globalization kò si à̀àyè láti fihàn idi ohùn pàtàkì ìẹ́ ìtúmọ̀.

Ìyí ọ̀rọ̀ padà sí èdè mìíran e kókó bí a bá fẹ́ òwò to lére pẹ̀lu awọn orílẹ̀-èdè mìíran.

ùgbọ́n, ní ọ̀pọ̀lópọ̀ ìgbà, ìẹ́ ìtúmò kò ni dárató.

Bí o ti wu ko pẹ́ to, Ìẹ́ ìtúmọ̀ ti kò dára lè e àkóba fún àwòrán ìlé-ìẹ́ àti fún ìgbẹ́kẹ́lé tí awọn ènìyàn ní sí. Ẹ̀bùn láti lè kọ́ oríiríi èdè

Ìlé-Ẹ̀kọ́ àkọ́mọ̀lédè ATT Communication ńe ìfilọ̀, ìyí ọ̀rọ̀ padà sí èdè mìíran gẹ́gẹ́bi ìyọrí si,a lè e ìranlọ́wọ́ fún yín,nípa ọ̀rọ̀ ẹnu tàbí ni kikọ́ sílẹ̀ nínú èdè tí ẹ bá yàn láàyo.

Eyi ni ìmọ̀ye, ìmọ̀ tí aini awọn ẹgbẹ́ àti òẹ́ ìjọba nínú ìpinnu ìrídi nńkan pẹ̀lú ìyọrísi wa gba wa láàye látí sunmọ́ yín,fún ìreti ìtùmọ́ pẹ̀lúpelú.Lákótán, agbára wa pilẹ̀ lórí ìmọ̀ nńkan sìsọ́ tàbí kikọ́ ki ìtúmò èdè to dì yíyàn.

Ìmọ̀ wa fún wa lágbára láti lè kọjúsí ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ àwon kóko ọ̀rọ̀ tí a ńsọ̀rọ̀ lé lórí gégẹ́bí ofin, ètò-inọ́nwó, ìmọ̀-ẹ̀rọ̀, àtí bẹẹ, bẹẹ lọ, ọlá egbẹ́ ọgbọ̀ntarìgì olùtúmọ̀ èdè wa ńla ńla.

Ní ìwọ̀-òórùn Àfíríkà, ìdá-àpó idi mẹ́́jọ àwọn ìẹ́ ìtúmọ́ jẹ́mọ èdè Faransé àti èdè Gẹ̀ẹ́si.

Awọn ọgbọ̀ntarìgì ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ètò ọrọ̀-ajé,ị̀únna àtí awọn oríirísi ètò mìíran ńiẹ́ pẹ̀lu wa, láti lè tẹ́ yín lọ́rùn,lórí ohùn kọ̀ọ̀kan tẹ bá nílò.

 
Ile
PDF tẹ ìwé Ijiṣẹ-iwe

ATT Communication kò ní àfiwé,fún gbogbo ẹgbẹ́ àti fún ẹnìkọ̀ọ̀kan ti o fẹ́ jáfáfá,nínú ìsẹ́ ní ode òní làárin àwọn orílẹ̀-èdè tàbí ní àyíká wa.

Látí bi ọdún márùnún sẹhìn ni Ilé-ìṣẹ́ ATT Communication ti ńe ore atílẹhìn, fún ọgọgọrùn ọkẹ́ aimọyé ẹgbẹ́ àti orí látí gbogbo oríirísi ìlé-ìẹ́, ẹgbẹ́ ní orílẹ̀-èdè, ikọ̀ ìjọba, ilé-ẹ̀kọ́, ilé ìfowópamọ, atí olùtọjú owó.

 
Nípa wa
PDF tẹ ìwé Ijiṣẹ-iwe

Ilé-ìṣẹ́ ATT Communication pàtàkì ní kikọ́ èdè àti ìyí ọ̀rọ̀ padà sí èdè mìíran, ìtúmọ̀, bakan naa nínú pé kí a e àmúwa afihàn ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ èdè lórí ètò lóríiríi.

ATT Communication kò ní àfiwé,fún gbogbo ẹgbẹ́ àti fún ẹnìkọ̀ọ̀kan ti o fẹ́ jáfáfá,nínú ìsẹ́ ní ode òní làárin àwọn orílẹ̀-èdè tàbí ní àyíká wa.

ATT Communication ní ẹ̀gbẹ́ olùkọ́ ìfọ̀rànlọ̀ àti olùkọ́ èdè to dangajía ti wọn si mọ̀ fún ipè wọn lórí ìẹ́ wọn.

Látí bi ọdún márùnún sẹhìn ni Ilé-ìṣẹ́ ATT Communication ti ńe ore atílẹhìn, fún ọgọgọrùn ọkẹ́ aimọyé ẹgbẹ́ àti orí látí gbogbo oríirísi ìlé-ìẹ́, ẹgbẹ́ ní orílẹ̀-èdè, ikọ̀ ìjọba, ilé-ẹ̀kọ́, ilé ìfowópamọ, atí olùtọjú owó.

ATT Communication ńe ìfìlọ̀ ìtànkálẹ̀

  • Èdè kikọ́
  • Ìtúmọ̀
  • Gbédègbẹ́yọ̀
  • Etò ìmúwa ọ̀pọ̀ èdè lórí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán

 
Gbédègbẹ́yo
PDF tẹ ìwé Ijiṣẹ-iwe

Olùrẹ̀pọ̀ amòye tí o mọ̀ nǹkan dajú akaaka

Ọ̀pẹ́ pàtàkì fún ìmọ̀ kíkún ti a ní nípa ayé fifẹnusọ ifihán ni gbàngbà, a lè jíẹ́ gbogbo ohùn tẹ bá fẹ́ láìbìkítà fún ìòro ìẹ́ tẹ fẹ́ kí a jíẹ́.

A tún lè tẹsíwájú nípa isopọ̀ ọpọ̀lọ́pọ̀ awọn agbára wa, láti lè pèse ìẹ́ ìgbufọ tó daráju, bótilẹ̀jẹ́pé a tùn máa e àkorí ohùn t́í o ẹlẹ̀ ní onírúurú èdè lẹ́ẹ̀kanna.

Ní apá kan agbára tiwa jóko lórí ìmọ̀ ijìnlẹ̀ fún ohún ti a sọ̀ àti àsìkò ti o sẹlẹ̀.

Ní idakéjì ni ti ànfàní wa láti lè e àpèjúwè ohùn tí o ẹlè ní oríiríi èdè laísí àdánù ọ̀rọ̀ ti a sọ̀ fun ni laígbagbè èrò-ọ̀kàn ẹniti o sọ̀rọ̀. Lákótan a ní ìmọ̀dájú nípa èdè.

Ìrírí ńla ńla ta ní, fún wa ni ànfàni láti lè sọ̀rọ̀ lórí onírúuru kóko ọ̀rọ̀, bí ofin,ìèlú, ìúnna, ìmọ̀-ẹ̀rọ̀ àti bẹẹ bẹẹ l̄ọ…

 
Eto Amóhùnmáwòrán
PDF tẹ ìwé Ijiṣẹ-iwe

Láti bí ọdún mẹ́ta sẹhin, ni ATT Communication e ifun kakiri eyi ti o ju ọgọrun wákàtí lọ lorí afẹ́fẹ́ àti lórí ẹ̀rọ́ àmóhùnmáwòrán ni Benin

Lákọ́kọ́ a kọjúsí ìfihan àà lórí ẹ̀rọ́ àmóhùnmáwòrán ní èdè abíníbí. Níìsìnsìnyì ATT Communication ńẹ́ lórí ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ àwọn ètò-àmóhùnmáwòrán. Pèlú ìrírí titóbi ti a kópọ̀ nínú ìẹ́ wa,oríiríi oníbàrà ti gbẹ́kẹ̀lé wa, a sì ti ní ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ àwon ètò tí awa paapa gbe] jàde.

A ńẹ́ timọ́timọ́ pẹ̀lú gbogbo àwọn ẹni tí ìẹ́ jẹ́ lóògún,láti ìpìnlẹ́ títí dé àmúwa ohùn tẹ bẹ́ wa.Iyen ni láti ẹ dájú àyọrísí to kùn ni lójú ní gbogbo ìgbà.

Pẹ̀lú àwọn ìẹ́lọ́ọ́, ìlànà-ìẹ́ tí o dárajù àti ẹ̀bùn ìmọ̀,a lè pèse àwọn ọna abáyọ̀ aèparí nípa àwọn èrò inú. A sì lè gbà àwọn ìẹ́ titayọ sílẹ̀ lórí oríiríi kóko ọ̀rọ̀.

 

Fún ẹ̀kún rẹrẹ àláyé ẹ jọ̀wọ́, e pè:

ATT Communication

02 BP 2579

Cotonou

Tel:( 229) 66 99 43 05

Orilẹ̀-Èdè Olóminira Benin