|
Nípa wa
|
|
|
Ilé-ìṣẹ́ ATT Communication pàtàkì ní kikọ́ èdè àti ìyí ọ̀rọ̀ padà sí èdè mìíran, ìtúmọ̀, bakan naa nínú pé kí a ṣe àmúwa afihàn ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ èdè lórí ètò lóríṣiríṣi. ATT Communication kò ní àfiwé,fún gbogbo ẹgbẹ́ àti fún ẹnìkọ̀ọ̀kan ti o fẹ́ jáfáfá,nínú ìsẹ́ ní ode òní làárin àwọn orílẹ̀-èdè tàbí ní àyíká wa. ATT Communication ní ẹ̀gbẹ́ olùkọ́ ìfọ̀rànlọ̀ àti olùkọ́ èdè to dangajía ti wọn si mọ̀ fún ipè wọn lórí ìṣẹ́ wọn. Látí bi ọdún márùnún sẹhìn ni Ilé-ìṣẹ́ ATT Communication ti ńṣe ore atílẹhìn, fún ọgọgọrùn ọkẹ́ aimọyé ẹgbẹ́ àti orí látí gbogbo oríṣirísi ìlé-ìṣẹ́, ẹgbẹ́ ní orílẹ̀-èdè, ikọ̀ ìjọba, ilé-ẹ̀kọ́, ilé ìfowópamọ, atí olùtọjú owó. ATT Communication ńṣe ìfìlọ̀ ìtànkálẹ̀
|