|
Ìtúmo
|
|
|
Ní ayé globalization kò si à̀àyè láti fihàn idi ohùn pàtàkì ìṣẹ́ ìtúmọ̀. Ìyí ọ̀rọ̀ padà sí èdè mìíran ṣe kókó bí a bá fẹ́ ṣòwò to lére pẹ̀lu awọn orílẹ̀-èdè mìíran. Ṣùgbọ́n, ní ọ̀pọ̀lópọ̀ ìgbà, ìṣẹ́ ìtúmò kò ni dárató. Bí o ti wu ko pẹ́ to, Ìṣẹ́ ìtúmọ̀ ti kò dára lè ṣe àkóba fún àwòrán ìlé-ìṣẹ́ àti fún ìgbẹ́kẹ́lé tí awọn ènìyàn ní sí. Ẹ̀bùn láti lè kọ́ oríṣiríṣi èdè Ìlé-Ẹ̀kọ́ àkọ́mọ̀lédè ATT Communication ńṣe ìfilọ̀, ìyí ọ̀rọ̀ padà sí èdè mìíran gẹ́gẹ́bi ìyọrí si,a lè ṣe ìranlọ́wọ́ fún yín,nípa ọ̀rọ̀ ẹnu tàbí ni kikọ́ sílẹ̀ nínú èdè tí ẹ bá yàn láàyo. Eyi ni ìmọ̀ye, ìmọ̀ tí aini awọn ẹgbẹ́ àti òṣìṣẹ́ ìjọba nínú ìpinnu ìrídi nńkan pẹ̀lú ìyọrísi wa gba wa láàye látí sunmọ́ yín,fún ìreti ìtùmọ́ pẹ̀lúpelú.Lákótán, agbára wa pilẹ̀ lórí ìmọ̀ nńkan sìsọ́ tàbí kikọ́ ki ìtúmò èdè to dì yíyàn. Ìmọ̀ wa fún wa lágbára láti lè kọjúsí ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ àwon kóko ọ̀rọ̀ tí a ńsọ̀rọ̀ lé lórí gégẹ́bí ofin, ètò-inọ́nwó, ìmọ̀-ẹ̀rọ̀, àtí bẹẹ, bẹẹ lọ, ọlá egbẹ́ ọgbọ̀ntarìgì olùtúmọ̀ èdè wa ńla ńla. Ní ìwọ̀-òórùn Àfíríkà, ìdá-àpó idi mẹ́́jọ àwọn ìṣẹ́ ìtúmọ́ jẹ́mọ èdè Faransé àti èdè Gẹ̀ẹ́si. Awọn ọgbọ̀ntarìgì ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ètò ọrọ̀-ajé,ị̀ṣúnna àtí awọn oríṣirísi ètò mìíran ńṣiṣẹ́ pẹ̀lu wa, láti lè tẹ́ yín lọ́rùn,lórí ohùn kọ̀ọ̀kan tẹ bá nílò. |